E Ti Tobi To Jesu Lyrics by EmmaOMG Ft Pelumi Deborah

EmmaOMG and Pelumi Deborah Lyrics

Dive into the heartfelt lyrics of “E Ti Tobi To Jesu” by EmmaOMG featuring Pelumi Deborah and experience the powerful message it conveys.

Cover art for E Ti Tobi To Jesu by EmmaOMG featuring Pelumi Deborah
E Ti Tobi To Jesu Cover Art

Oluwa tobi ni sioni
O si joba lori gbogbo orile ede
Je ki won yin oruko re ti o tobi ti osi leru
Oh my God

Gbogbo aye n wariri ni oruko re
Won nkorin
Eti tobi to oo
Jesuuuuu
Awon orun n seleri won foribale niwaju ite re o, won so wipe
Eti tobi to oo
Jesuuuuu
Won ni Eti tobi to o

Oh oh oh oluwa
Eti tobi to oo
Jesuuuuu
Won ni eti tobi to o
Oh oh oh oh oluwa wa o
Eti tobi to oo
Jesuuuuu
Awon oke nla nla won foribale o
Tori iwo ni ogo ati ola ju oke nla ikogun won ni lo o
Eti tobi to o

Jesuuuuu
Iwo ti olorun ji dide ninu oku lati gba wa kuro ninu ibinu ti n bo o
Eti tobi to o
Jesuuuuu
Iwo oluwa olorun to n gbe larin awon kerubu to po ni ipa ati agbara o
Eti tobi to oo
Jesuuuuu
Ani gbogbo aye n wariri ni oruko re won nkorin, yeee
Eti tobi to oo

Jesuuuuu
Awon orun n seleri won foribale niwaju ite re
Eti tobi to oo
Jesuuuuu
Eti tobi to o
oh oh oh oh oluwa wa o
Eti tobi to o

Jesuuuuu
Ipekun ola , Ipekun iye ye eh eh eh eti tobi to oh oh oh oh
Eti tobi oo
Jesuuuuu
Ireti wa o, eri wa o oh oh oh eti tobi to oh oh oh
Eti tobi to ooo
Jesuuuuu
Itan sho to wole ro ro ro ro ro Eti tobi to aye ati orun n bo oo
Won n juba, eti tobi to o Jesuuu (won foribale)
Jordani ri o o pada seyin ,okun ri o o sa Eti tobi to olodumare
Eti tobi to o

Jesuuuuu
Abetilukarabiajere baba mi agba oye
Eti tobi to oh oh oh oh oh
Eti tobi oo
Jesuuuuu
Tori na gbogbo aye n wariri ni oruko re won nkorin
Eti tobi to o
Jesuuuuu
Awon orun n seleri won foribale niwaju ite re eh eh eh
Eti tobi to o
Jesuuuuu

Won ni eti tobi to oo oh oh oh oluwa wa
Eti tobi to oo
Jesuuuuu
Gbogbo idile Jesse
Jesu won nkorin foribale won so wipe
Eti tobi to o
Jesuuuuu
Ipekun ola Ipekun oro
Ipekun agbara oh eti tobi to
Eti tobi to oh oh oh oh oh
Eti tobi to o
Jesuuuuu
Ore ati ola nla ni o wa ni iwaju re
Ipa ati ewa nbe nibi mimo re

Eti tobi to o
Jesuuuuu
Aiikakatan o, aiibubutan o atobi loye ongbe leyin eni a n da loro oo
Eti Eti Eti tobi to o
Eti tobi to o
Jesuuuuu
Jesu gbogbo aye n wariri ni oruko re won nkorin
Eti tobi to oo
Jesuuuuu
Awon orun n seleri won foribale niwaju ite re ohhhh eh
Eti tobi to oo
Jesuuuuu

Won juba fun ajunilo o, eba n juba f’ajunilo eh
E ba n seba f’ajunilo o, e ba gbo’suba f’ajunilo
E ba n gbo osuba f’ajunilo o, e ba n kira f’ajunilo o
E ba n juba f’ajunilo o
E bami juba f’ajunilo e ba n gbo’suba f’ajunilo o
E ba n seba f’ajunilo o
Ani gbogbo aye n wariri ni oruko re won nkorin
Eti tobi to o Jesuuuuuuuuu
Oh My God

Find and explore lyrics from other music genres here

Get Fresh updates as they drop via Twitter and Facebook

TAGS

Shout out link

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *